audio audioduration (s) 2.16 10.5 | text stringlengths 21 93 | speaker_id int64 1 1 |
|---|---|---|
Ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn dèrò àtìmọ́lé torí nílùú Ìbàdàn. | 1 | |
Ìyàwó àwọn ọlọ́pàá tó kú lásìkò ìwọ́de tó kọjá ti bẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́ | 1 | |
Nítori ọrọ táa sọ lọ́jọ́sí ni Túndé yoo fi kúrò nílé ìwé. | 1 | |
Ilẹ̀ mímìtìtì ní ìlú ṣakí ti sọ àwọn olugbé ibẹ̀ sínú hílàhílo | 1 | |
Ìgbòho ní Aláàfin, Ọ̀ọ̀nì, Olúbàdàn tì òun lẹ́yìn. | 1 | |
Àfáà ń wáàsù kí àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ má gba abẹ́rẹ́ àjẹ́sára. | 1 | |
Awọn gómìnà kankan ti padà sí ẹgbẹ́ òṣèlú onígbàálẹ̀. | 1 | |
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló fẹ́ kúrò nílè Nàíjíríà. | 1 | |
Ọba ìlú wa kìlọ̀ fún áwọn ọ̀dọ́ lórí ṣíṣe òògùn owó òjijì. | 1 | |
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀dọ́ lọ́ fẹ́ fi orílẹ̀ èdè Nàìjíríà sílẹ̀. | 1 | |
Àwọn àjẹ́ ló wà nídí ọ̀rọ̀ Àrẹ̀mú. | 1 | |
Oṣù kan péré ni Àjídé fi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Adélékè. | 1 | |
Àtisùn ti dogun torí ọ̀rọ̀ àbò ní orílẹ-èdè yìí. | 1 | |
Ìwádìí fi hàn pé ikú àrá ló pa àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba mẹ́ta kan. | 1 | |
Àwọn ẹ̀yà Yorùbá máa ń pé ara wọn ní ọmọ ilẹ̀ káàárọ̀-ò-jíire. | 1 | |
Ẹgbọ́n mi ni Ọlápọ̀si, ó ní ìyàwó méjì, àti ọmọ mẹ́ta. | 1 | |
Ọ̀rẹ́bìnrin méjì ti para wọn torí wọ́n ba ọkọ ara wọn sùn. | 1 | |
Ajá mẹ́ta ló ń ṣọ́ ilé ọ̀gá ọlọ́pàá tó wà ní Yemẹtu Ìbàdàn | 1 | |
Ẹ̀sùn bíbá ọmọdé tage kò yẹ àgbàlagbà ọkùnrin | 1 | |
Àwọn ìlànà yìí yóó ṣe ìrànwọ́ fún àwọn ènìyàn. | 1 | |
Ìjà wọn ò ṣeé dá sí kí wọn má baà yi lé èèyàn lórí. | 1 | |
Ó jọ bí ẹni pé alága ẹgbẹ́ Iréwọlédé ni Ọlátúndé Adégbuyì | 1 | |
Ṣèyí fojú hàn n'íta fún ìgbà àkọ́kọ́ lẹ́yìn tó ṣẹ́gun ọ̀tá. | 1 | |
Ìjọba Ọ̀sun ní abẹ́rẹ́ àjẹsára lọ́wọ́. | 1 | |
Bùnmi tún parọ́ pé òun kọ́ lòun wa ọkọ̀ sáré àsájù. | 1 | |
Gbogbo àwọn ọmọbìnrin ló nílò ìtọ́jú tó dára. | 1 | |
Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ti ń kọ́ àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe lè dìbò | 1 | |
Iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣe kókó lásìkò yìí. | 1 | |
Ǹjẹ́ o mọ̀ nípa Bídèmí tó wọ gàu ní Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn jì̀bì̀tì̀ | 1 | |
Àwọn adarí ilé iṣẹ́ náà ni ó ń fa wàhálà fún àwọn òṣìṣẹ́ náà. | 1 | |
Kò séwu fún gbogbo àwọn tí yóò kópa nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ní Èkó. | 1 | |
Ìforúkọ sílẹ̀ ti ń lọ lórí ayélujára láti di ọlọ́pàá. | 1 | |
Ohun tó ṣẹlẹ̀ níbi àjọ̀dún ẹgbẹ́ wa kọ́wa lọ́gbọ́n gidigidi. | 1 | |
Ẹgbẹ́ ọlọ́dẹ pariwo síta lórí ìlànà ìgbanisíṣẹ́ ìjọba. | 1 | |
Mó mu àwọn àlàyé àti ìmọ̀ràn yí ni pàtàkì nínú ìgbésí ayé mi. | 1 | |
Wọ́n sọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ níbi ètò tí mo lọ lọ́jọ́ ìsinmi tó kọjá | 1 | |
Adìyẹ kan yàgbé sí orí ọkọ̀ mi. | 1 | |
Ọlá ń kírun lọ́wọ́ ni wọ́n ta ní ìbọn. | 1 | |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kó ẹgbẹ̀rún ìrẹsì fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba. | 1 | |
Adédoyin ló ni ilé ìtura tó wà lọ́nà Yemẹtu ní Ìbàdàn | 1 | |
Ìpàdé ìdìbò ẹgbẹ́ òṣèlú wa máa wáyé ní ìlú Ìsánlú lọ́túnla | 1 | |
Àwọn ọlọ́sìn ẹja ní àìríṣẹ́ṣe ló fà gbogbo oun tó ṣẹlẹ̀. | 1 | |
Èèyàn mẹ́rin kú ní Nàíjíríà lónìí. | 1 | |
Ta ló fipá bá Fúnkẹ́ lò pọ̀ ní ìlú Ọ̀ṣun? | 1 | |
Babaláwo Ìgbòho sọ pé àwọn agbófinró ti gbé aṣọ òun lọ. | 1 | |
Ìjà wáyé láàrin ọ̀rẹ́ tímọ́-tímọ́ méjì. | 1 | |
Bọ̀sú ti padà yọjú sí àgọ́ ọlọ́pàá lẹ́yìn tí wọ́n ráṣẹ́ pè é. | 1 | |
Ó ní kí ìjọba àpapọ̀ náà ṣé àtúnṣe. | 1 | |
Kì í ṣe nǹkan tuntun kí agbábọ́ọ̀lù kú sórí pápá. | 1 | |
Ìyáàfin Olúwalóní ti bèèrè fún owó ìtanràn lọ́wọ́ ọlọ́pàá. | 1 | |
Ilé-ìwé gíga Èkó ti gba Bùsáyọ̀ wọlé. | 1 | |
Àwọn mẹ́fà kú nínú àwọn sójà tí ó lọ jà fún ìlú. | 1 | |
Ewu wo làwọn òṣìṣẹ́ elétò ìlèra ń kojú ní Nàìjíríà? | 1 | |
Ikú ààrẹ̀ ìjọ́sí jẹ́ oun tó dun gbogbo ìlú gidigidi. | 1 | |
Bọ́lá fẹ́ ja mí lólè, ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò gbà fún-un | 1 | |
Bàbá mi kọ̀ láti bá mi sọ̀rọ̀ torí ọ̀kọ akáta tí mo mú wálé | 1 | |
Wọ́n gbà pé owó ni àwọn ará Èkó ń lé, wọn kò ní Ọlọ́run. | 1 | |
Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Ọ̀ffa fàákékọ́rí lórí ìwọ́de náà. | 1 | |
Àwọn olórin tún máa ń mọ ìtàn nípa èèyàn, ìdílé àti ìlú lápapọ̀. | 1 | |
Ẹyọ kan ṣoṣo ló wá láti tọ̀jú aláìsàn nínú àwọn òṣìṣẹ́ náà. | 1 | |
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti gbé ìlànà mìíràn láti fi ṣe ìsìnkú ọba. | 1 | |
Ọ̀dọ̀ fásitì kan ní ìlú Èkó ló ṣe òògùn ìtura yìí. | 1 | |
Ọlọ̀pàá yin àwọn aráàlú tí wọ́n kígbe síta. | 1 | |
Nkò le ṣeré pẹ̀lú ọkùnrin tí mi ò mọ rí lẹ́yìn ìgbeyàwó mi | 1 | |
Ọkọ ọbabìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sí àti àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n pé jọ | 1 | |
Báwo ni àwọn ikọ̀ yìí yóó ṣe dáná sun ara wọn? | 1 | |
Wọ́n má ń fipá bá obìnrin kan lòpò láàárín wákàtí mẹ́ta. | 1 | |
Ọmọ tó bí sọ́gbà ẹ̀wọ̀n ló kọ̀kọ́ gba ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́. | 1 | |
Àwọn ọmọ náà jẹ àgbàdo lójú títì. | 1 | |
Ẹni tó dábàá èlé owó epo ti tún bá ìjọba já nítorí àríyànjiyàn | 1 | |
Ìgbà tí wọ́n dé Ìbàdàn, wọ́n kọ́ ilé sí agbègbè Mọ̀lété. | 1 | |
Iṣẹ́ ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu fún Àmọ̀tẹ́kùn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. | 1 | |
Ọ̀lọ́pàá sọ pé ìjọba àpapọ̀ kò ran àwọn lọ́wọ́ tó bó ṣe yẹ | 1 | |
Alágbádá ti gbóṣùbà fún Gbóyèga Fámọdún kó tó gbée lọ sílé ẹjọ́ | 1 | |
Tàlàbí ní ìwọ́de kọ́ ni Ààrẹ ọ̀nà Kakańfò fi ń bẹ̀rẹ̀ ogun. | 1 | |
Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti wó. | 1 | |
Àwọn Adigunjàlè kọlu ilé-ìfowópamọ́ ní Ọṣun. | 1 | |
Ṣèyí Mákindé ti yọ àwọn olùkọ́ kúrò nípò. | 1 | |
Mo ti gbà fún Ọlọ́run níbi tí mo wà báyìí ni Ìgbòho sọ. | 1 | |
Àwọn jàndùkú jí agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà méjì gbé lópòpónà. | 1 | |
Ìjọba àpapọ̀ ti ra abẹ́rẹ́ àjẹsára onígbá méjì ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá. | 1 | |
Ìyà ló ń jẹ àwọn nọ́ọ̀sì ní Ọ̀wọ̀ tí wọ́n fi ń bínú. | 1 | |
Ẹni ṣiṣẹ́ jàre ìṣẹ́ ni àwọn Yorùbá máa ń wí. | 1 | |
Àwọn àwòrán tí wọ́n yà níbi ìgbéyàwó ọmọ ààrẹ kò dára. | 1 | |
Jọ̀wọ́ bá mi kí ìyá wa pẹ̀lú ọmọ pupa mi, Oyindàmọ́lá. | 1 | |
Ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ọmọ ìlú lái dìbò yan aṣojú wọn. | 1 | |
Ọkùnrin méjì ló fi mágùn sí orí ìyàwó rẹ̀ ní Bashọ̀run | 1 | |
Ẹlòmíìran ń fi irú ọyàn wa tọrọ. | 1 | |
Àjọ aṣọ́nà kìlọ̀ f'áwọn awakọ̀ tó máa tẹ fóònù lórí ìrin ní Èkó. | 1 | |
Gómìnà Bùkọ́lá fún Dókítà ní àmì ẹ̀yẹ fún ìṣẹ́ takuntakun. | 1 | |
Ìdájọ́ òdodo nìkan ni mò ń bèèrè fún lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Ìjẹ̀ṣà. | 1 | |
Kò sí ààyè láti fẹ́ran Akérédolú ju Arígbábuwó lọ | 1 | |
Ọ̀rẹ́ bí ọmọ ìyá ni èmi àti Ìfẹ́dọ̀lápọ̀, alábáárò mi ni ó ń ṣe. | 1 | |
Ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàdọ́ta kan ló pa ọkọ ẹ̀ nítorí owó | 1 | |
Tọ́lá tún wá sí ààfin láìmú ọkọ wá. | 1 | |
O ti tó àádọ́ta ọdún tí a ti fi ẹ̀sùn kan Ìgbòho àti Káyọ̀dé | 1 | |
Àwọn agbénipa tí wọ́n jí ọmọ náà gbé ní ojú pópó lásán ló paá | 1 | |
Àlékún bá iye owó búrẹ́dì ní ìlú Èrúwà. | 1 | |
Kí gan-an láwọn nǹkan tó n fa àìsàn ibà ní àgọ̀-ara? | 1 | |
Dọ́kítà kan ti sọ àwọn ìdí tí obìnrin fi dára ju ọkùnrin lọ. | 1 |
End of preview. Expand in Data Studio
No dataset card yet
- Downloads last month
- 6